ORIKÍ YÁMI OXORONGÁ
Okiti Kata, Ekùn A Pa Eran Má Ni Yan 
Olu Gbongbo Ki Osun Ebi Ejè 
Gosun-gosun On Wo Ewu Ejè 
Ko Pá Eni Ko Je Oka Odun 
A Ni Esin O Ni Kange 
Odo Bara Oto lu 
Omi a Dake Je Pa Eni 
Omo Opara Oga Ndanu, Sese Iba o ! 
Iba Ìyàmì o ! 
NiMo Mo Je Ni Ko Je Ti Aruní 
Emi Wa Foribale Fun Sese 
Olu idu Pe O papa 
Ele Adie Ko Tuka 
IyaTemi Mi Ni Bariba Li Akoko 
Emi Ako Ni Ala Mo Le Gbe Agada 
Emi A Wa Kiyà Onile Ki Ile. 
Ìbà Ìyàmì o ! 
Asé O !